The Madonna of the Streets
Mary's Rosaries

Home Page

Contact Us

Make a Payment, Methods of Payment, Refund and Exchange Policies

Rosaries
subpages:

How to Pray the Rosary
subpages:

Pictures Main Page
subpages:

Curriculum
subpages:

Website Terms of Use

License Agreement

Sitemap


The Work of God's Children

  Yoruba Rosary Prayers
This language is also known as Yooba, Yariba, and Ede-Yoruba.

This language is spoken by 18,850,000 people in Oyo, Ogun, Kwara, Ondo Osun and Lagos states and in Kogi state in Nigeria.  It is also spoken in Benin, Togo, the United Kingdom, and the United States of America.

See also The Work of God's Children page for the illustrated version of prayers in this language.

Apostoli ti crèdi / Apostles' Creed

Mo gba olohun gbor, baba a unla, èniti oda ayé ati orun.

Ati Jesu Christi, omon olohun ti Maria bi, to jouya la bè Pilatou, ti won kan lériv agbélébou, oku ojor kèa ojidé, olor oké olor joko lapka otun Edumaré, ibi ti ogbé la ti dajor wa lorjor idjidé.

Mo gba gbor ninou mimon, ninou churchi catoliki, idariji èchè ti idjidé omon éniyan. Ami.

Iwé ti Nicé / The Nicene Creed

Mo gba gbor niou olohun kan chocho, baba wa unla, ti oda ayé ati orun, ati unti ari ati yé a iri.

Ninou Jesu Christi kan , omor olorhun kan chocho, ti olohun bi shaju gbogbo éniyan; olorhun awon olorhun; ti oba olorhun chichè lati da ilé ayé ta wa Eniti toriwa awa ormon éniyan; owa ilé ayé lati gba awon èchè wa, ti Maria bi guèguè bi ormon éniyan; on kan léri agbélébou, ojouya labè Pilatou, on kpa; ojorkèta oji undé otoun gba gbara kun ghèguè bi awon iwé sor, ogoké lor olor joko lapka otun Edumaré, ibiti okoro la ti dajor omor éniyan.

Mo gba ninou iwé mimon, èniti to da wa, baba ti fid é léri awon ormoun, ti awoon èsor.

Mo gba gbor ninou chuchi catoliki ati apostolic. Mo gba ninou ojor ibi yé kan , ninou idari èshè, mo douro é ojor idjidé awon okou; ati agéssa yé lor. Ami.

Another version of
The Nicene Creed

Baba Olódùmarè, eni tí ó dá òrun òun ayé,
àti ohun gbogbo tí a n rí àti èyí tí a kò rí.

Mo sì gba Olúwa kan soso gbó, Jésù Krístì,
eni kan soso tí í se Omo bíbí Olórun.
Eni tí Baba ti bí síwájú ìbèrè ayé gbogbo.

Olórun láti inú Olórun wá, ìmólè láti inú ìmólè.
Olórun tòótó láti inú Olórun tòótó.
Eni tí a bí sùgbón tí a kò dá,
tí ó ní ìwà kan náà pèlú Bàbá,
tí a sì tipa rÆ dá ohun gbogbo.
Eni tí ó torí àwa ènìyàn àti ìgbàlà wa
sòkalè láti òrun wá,
(Kí gbogboògbò teríba níhìn-ín)
tí ó sì gba ara ènìyàn láti inú Màríà Wúndía
nípa agbára Èmí Mímó, tí a sì so ó di ènìyàn.
(A ó gbé orí sókè léyín náà)
A kàn án mó àgbélébùú nítorí wa,
ó jìyà ikú lówó Pøntíù Pílátù, a sì sìn ín.
Ní ojó keta ó jínde gégé bí ìwé mímó ti wí,
ó sì gòkè re òrun, ó jókòó lówó òtún Bàbá,
yóò sì tún padà pèlú ògo láti dá ààyè òun òkú léjó.

Ìjoba rè kì yóò sì ní ìpèkun.
Mo sì gba Èmí Mímó gbó, Olúwa àti olùfún-ni ní ìyè,
eni tí o ti òdò Bàbá àti Omo jáde wá,
tí ó jé pé òun pèlú Bàbá àti Omo ni a n fi ìbo fún,
tí a sì n yìn ní ògo; Eni tí ó ti enu àwon wòlíì sòrò.

Mo sì gba Ìjo ènìyàn Olórun kan soso gbó,
tí ó jé mímó, Kátólíkì àti Àpóstólíkì.
Mo jéwó ìwèrí kan soso fún ìmúkúrò èsè.
Mo sì n retí àjínde àwon òkú, àti ìyè ayé tí n bò wá.

Àmín.

Bàbá Mì / Our Father

Bàbá mì
mo fi ara mi lé Ọ lọ́wọ́.
Èmí dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ
fún ohun ti mo jẹ́ látì ọ́wọ́ rẹ.
Èmí ṣe tán láti gba ohunkóhun
láti ọ́wọ́ rẹ.
Èmí kò ní èrò ọkàn míràn, Ọlọ́run mi,
ju pé kí èmí àti gbogbo èdá rẹ
kí á ṣe ìfé rẹ.
Mo fi ẹ̀mí mi lé Ọ lọ́wọ́.

Mo fi í fún Ọ, Olọ́run mi,
tìfẹ́tìfẹ́ pẹ̀lú gbogbo ìfẹ́ ọkàn mi.
Ìfẹ́ mi nfà mí látì fi ara mi fún Ọ pátápátá
pẹ̀lú ìgbẹ́kẹ̀lé aìnípẹ̀kun,

Amém.

Olórun Mi / Act of Contrition

Olórun mi, tokàn tokàn ni èmí fi kóríra èsè mi nítorí wón a máa bà ó nínú jé.
Nítorí ìwó dára ju ohun gbogbo lo, ìwo a sì máa kóríra èsè pátápáta.
Mo pinnu gírí nípa ìrànlówó oore-òfè re láti má tún bà ó nínú jè mó,
àti láti se ètùtù fún èsè mi.  Àmín.


Creative Commons License
The contents of this webpage are licensed under a Creative Commons Attribution 3.0 License.
Valid HTML 4.01 Transitional
(this is the bottom of page)